Home > Terms > Yoruba (YO) > Ibeere ati idahun.

Ibeere ati idahun.

Ibeere ati idahun je ere idaraya kan tabi ere idaraya atinuwa ninu eyi ti awon olukopa awon olodonni tabi bi awon egbe n gbiyanju lati dahun awon ibeere ni ona ti o tona. Awon ibeere ati idahun tun je awon idanwo ranpe ti a nlo ninu eto eko ati awon ona miran ti o jo ara won lati se oduwon idagbasoke ninu imo, awon agbara lati se nnkan, pelu/tabi bi a ti mose to.

0
  • Part of Speech:
  • Synonym(s):
  • Blossary:
  • Industry/Domain: Education
  • Category:
  • Company:
  • Product:
  • Acronym-Abbreviation:
Collect to Blossary

Member comments

You have to log in to post to discussions.

Terms in the News

Featured Terms

Contributor

Featured blossaries

Knitting Designers

Category: Arts   2 20 Terms

Game of Thrones Characters

Category: Other   1 8 Terms